Isikiẹli 37:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí n tó ṣẹ́jú pẹ́, iṣan ti dé ara wọn, ẹran ti bo iṣan, awọ ara sì ti bò wọ́n, ṣugbọn kò tíì sí èémí ninu wọn.

Isikiẹli 37

Isikiẹli 37:2-13