Isikiẹli 37:6 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo fi iṣan bò yín lára; lẹ́yìn náà n óo fi ara ẹran bò yín, n óo sì da awọ bò yín lára. N óo wá fi èémí si yín ninu, ẹ óo di alààyè, ẹ óo sì mọ̀ pé èmi ni OLUWA.’ ”

Isikiẹli 37

Isikiẹli 37:4-14