Isikiẹli 37:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá sọ fún mi pé, “Sọ àsọtẹ́lẹ̀ fún àwọn egungun wọnyi, kí o wí fún wọn pé, ‘Ẹ̀yin egungun gbígbẹ wọnyi, ẹ gbọ́ ohun tí OLUWA wí’.

Isikiẹli 37

Isikiẹli 37:3-6