Isikiẹli 37:26 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo bá wọn dá majẹmu alaafia, tí yóo jẹ́ majẹmu ayérayé. N óo bukun wọn, n óo jẹ́ kí wọn pọ̀ sí i, n óo sì gbé ilé mímọ́ mi kalẹ̀ sí ààrin wọn títí lae.

Isikiẹli 37

Isikiẹli 37:20-27