Isikiẹli 37:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo bá sọ àsọtẹ́lẹ̀ bí ó ti pàṣẹ fún mi. Èémí wọ inú wọn, wọ́n sì di alààyè; ogunlọ́gọ̀ eniyan ni wọ́n, wọ́n bá dìde dúró!

Isikiẹli 37

Isikiẹli 37:8-12