Isikiẹli 37:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Agbára OLUWA sọ̀kalẹ̀ sára mi, ẹ̀mí rẹ̀ sì gbé mi wá sinu àfonífojì tí ó kún fún egungun.

Isikiẹli 37

Isikiẹli 37:1-2