Isikiẹli 36:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni ẹ óo ranti ìrìnkurìn ati ìwà burúkú yín, ara yín óo sì su yín nítorí ẹ̀ṣẹ̀ yín ati ìwà ìríra yín.

Isikiẹli 36

Isikiẹli 36:24-38