Isikiẹli 36:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn mo ní ìtara fún orúkọ mímọ́ mi, tí àwọn ọmọ Israẹli sọ di nǹkan yẹ̀yẹ́ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n wà.

Isikiẹli 36

Isikiẹli 36:18-23