Isikiẹli 36:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, o kò ní pa eniyan mọ́, o kò sì ní pa àwọn eniyan rẹ lọ́mọ mọ́, Èmi OLUWA Ọlọrun ni ó sọ bẹ́ẹ̀.

Isikiẹli 36

Isikiẹli 36:5-19