Isikiẹli 36:12 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo jẹ́ kí àwọn eniyan mi, àní àwọn ọmọ Israẹli, máa rìn bọ̀ lórí yín. Àwọn ni wọn óo ni yín, ẹ óo sì di ogún wọn, ẹ kò ní pa wọ́n lọ́mọ mọ́.

Isikiẹli 36

Isikiẹli 36:11-17