Isikiẹli 36:10 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo sọ àwọn ọmọ Israẹli tí ń gbé orí yín di pupọ. Àwọn ìlú yóo rí ẹni máa gbé inú wọn, wọn óo sì tún gbogbo ibi tí ó ti wó kọ́.

Isikiẹli 36

Isikiẹli 36:1-12