Isikiẹli 36:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní, “Ìwọ ọmọ eniyan, fi àsọtẹ́lẹ̀ bá àwọn òkè Israẹli wí. Sọ pé, ‘Ẹ̀yin òkè Israẹli, ẹ gbọ́ ohun tí OLUWA wí:

Isikiẹli 36

Isikiẹli 36:1-4