Isikiẹli 35:9 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo sọ ọ́ di ahoro títí lae, ẹnikẹ́ni kò sì ní gbé inú àwọn ìlú rẹ mọ́. O óo wá mọ̀ nígbà náà pé èmi ni OLUWA.

Isikiẹli 35

Isikiẹli 35:7-15