Isikiẹli 35:7 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo sọ òkè Seiri di aṣálẹ̀ ati ahoro. N óo pa gbogbo àwọn tí ń lọ tí ń bọ̀ níbẹ̀.

Isikiẹli 35

Isikiẹli 35:6-10