Isikiẹli 35:5 BIBELI MIMỌ (BM)

“ ‘Nítorí pé ò ń fẹ́ràn ati máa ṣe ọ̀tá lọ títí, o sì fa àwọn ọmọ Israẹli fún ogun pa nígbà tí ìṣòro dé bá wọn, tí wọn ń jìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn.

Isikiẹli 35

Isikiẹli 35:1-13