Isikiẹli 35:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ óo mọ̀ pé èmi OLUWA gbọ́ gbogbo ohun tí ẹ̀ ń sọ sí àwọn òkè Israẹli, pé wọ́n ti di ahoro ati ìkógun fun yín.

Isikiẹli 35

Isikiẹli 35:8-15