Isikiẹli 34:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, wọ́n túká nítorí pé wọn kò ní olùṣọ́, wọ́n sì di ìjẹ fún àwọn ẹranko burúkú.

Isikiẹli 34

Isikiẹli 34:1-10