Isikiẹli 34:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn óo mọ̀ pé èmi, OLUWA Ọlọrun wọn, wà pẹlu wọn, ati pé àwọn ọmọ Israẹli sì ni eniyan mi. Èmi OLUWA Ọlọrun ni mo sọ bẹ́ẹ̀.

Isikiẹli 34

Isikiẹli 34:22-31