Isikiẹli 34:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ń jẹ ẹran ọlọ́ràá, ẹ̀ ń fi irun aguntan bo ara yín, ẹ̀ ń pa aguntan tí ó sanra jẹ; ṣugbọn ẹ kò fún àwọn aguntan ní oúnjẹ.

Isikiẹli 34

Isikiẹli 34:1-11