Isikiẹli 34:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Olùṣọ́ kanṣoṣo ni n óo yàn fún wọn, òun náà sì ni Dafidi, iranṣẹ mi. Yóo máa bọ́ wọn, yóo sì máa ṣe olùṣọ́ wọn.

Isikiẹli 34

Isikiẹli 34:20-24