Isikiẹli 34:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi fúnra mi ni n óo jẹ́ olùṣọ́ àwọn aguntan mi, n óo sì mú wọn dùbúlẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni èmi OLUWA Ọlọrun sọ.

Isikiẹli 34

Isikiẹli 34:11-25