Isikiẹli 34:11 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA Ọlọrun ní, “Ẹ wò ó! Èmi fúnra mi ni n óo wá àwọn aguntan mi, àwárí ni n óo sì wá wọn.

Isikiẹli 34

Isikiẹli 34:10-20