Isikiẹli 33:7 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ọmọ eniyan, ìwọ ni mo yàn ní olùṣọ́ fún ilé Israẹli; nígbàkúùgbà tí o bá gbọ́ ọ̀rọ̀ kan lẹ́nu mi, o níláti bá mi kìlọ̀ fún wọn.

Isikiẹli 33

Isikiẹli 33:5-10