Isikiẹli 33:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Lójú wọn, o dàbí olóhùn iyọ̀ tí ń kọrin ìfẹ́, tí ó sì mọ ohun èlò orin lò dáradára. Wọ́n ń gbọ́ ohun tí ò ń wí, ṣugbọn wọn kò ní ṣe é.

Isikiẹli 33

Isikiẹli 33:25-33