Isikiẹli 33:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn óo wá mọ̀ nígbà náà pé èmi ni OLUWA nígbà tí mo bá sọ ilẹ̀ náà di ahoro ati aṣálẹ̀, nítorí gbogbo ìwà ìríra tí wọ́n ti hù.

Isikiẹli 33

Isikiẹli 33:19-33