Isikiẹli 33:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Idà ni ó kù tí ẹ gbẹ́kẹ̀lé; ẹ̀ ń ṣe ohun ìríra, ẹ̀ ń bá iyawo ara yín lòpọ̀, ẹ sì rò pé ẹ óo jogún ilẹ̀ yìí?

Isikiẹli 33

Isikiẹli 33:24-29