Isikiẹli 33:16 BIBELI MIMỌ (BM)

N kò ní ranti gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ tí o ti dá mọ́. Nítorí pé ó ti ṣe ohun tí ó dára, tí ó sì tọ́, yóo yè.

Isikiẹli 33

Isikiẹli 33:12-19