Isikiẹli 32:9 BIBELI MIMỌ (BM)

“N óo jẹ́ kí ọkàn ọpọlọpọ eniyan dààmú nígbà tí mo bá ko yín ní ìgbèkùn lọ sí ilẹ̀ tí ẹ kò dé rí, láàrin àwọn orílẹ̀-èdè ayé.

Isikiẹli 32

Isikiẹli 32:4-11