Isikiẹli 32:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí mo bá pa á rẹ́, n óo bo ojú ọ̀run; n óo jẹ́ kí ìràwọ̀ ṣóòkùn n óo fi ìkùukùu bo oòrùn lójú, òṣùpá kò sì ní tan ìmọ́lẹ̀.

Isikiẹli 32

Isikiẹli 32:4-9