Isikiẹli 32:5 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo sọ ẹran ara rẹ̀ káàkiri sí orí àwọn òkè. N óo sì fi òkú rẹ̀ kún àwọn àfonífojì.

Isikiẹli 32

Isikiẹli 32:1-9