Isikiẹli 32:22 BIBELI MIMỌ (BM)

“Asiria náà wà níbẹ̀, pẹlu gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ̀. Ibojì àwọn tí wọ́n ti kú yí i ká. Gbogbo wọn ni wọ́n ti kú ikú ogun.

Isikiẹli 32

Isikiẹli 32:14-27