Isikiẹli 32:20 BIBELI MIMỌ (BM)

“Wọn yóo ṣubú láàrin àwọn tí wọ́n kú ikú ogun; ogunlọ́gọ̀ àwọn eniyan rẹ̀ yóo ṣubú pẹlu rẹ̀.

Isikiẹli 32

Isikiẹli 32:17-21