Isikiẹli 31:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ó ga sókè fíofío, ju gbogbo igi inú igbó lọ.Àwọn ẹ̀ka rẹ̀ tóbi, wọ́n sì gùn,nítorí ọpọlọpọ omi tí ó ń rí.

Isikiẹli 31

Isikiẹli 31:1-9