Isikiẹli 31:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ẹyẹ ojú ọ̀run yóo kọ́lé sórí ìtì igi rẹ̀ tí ó wó lulẹ̀. Gbogbo ẹranko inú igbó yóo tẹ àwọn ẹ̀ka rẹ̀ mọ́lẹ̀.

Isikiẹli 31

Isikiẹli 31:3-16