Isikiẹli 31:10 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí pé ó ga sókè fíofío, góńgó orí rẹ̀ wọ inú ìkùukùu lójú ọ̀run, ọkàn rẹ̀ sì kún fún ìgbéraga nítorí gíga rẹ̀.

Isikiẹli 31

Isikiẹli 31:8-18