Isikiẹli 30:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn yóo mọ̀ pé èmi ni OLUWA nígbà tí mo bá dáná sun Ijipti, tí gbogbo àwọn olùrànlọ́wọ́ rẹ̀ bá ṣubú.

Isikiẹli 30

Isikiẹli 30:6-11