Isikiẹli 30:21 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ìwọ ọmọ eniyan, mo ti ṣẹ́ Farao, ọba Ijipti, lápá, a kò sì tíì dí i, kí ọgbẹ́ rẹ̀ fi san, kí ó sì fi lágbára láti gbá idà mú.

Isikiẹli 30

Isikiẹli 30:13-26