Isikiẹli 30:10 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA Ọlọrun ní, “N óo ti ọwọ́ Nebukadinesari, ọba Babiloni, fi òpin sí ọrọ̀ Ijipti.

Isikiẹli 30

Isikiẹli 30:2-17