Isikiẹli 30:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA bá mi sọ̀rọ̀, ó ní,

2. “Ìwọ ọmọ eniyan, sọ àsọtẹ́lẹ̀ kí o sì wí pé, OLUWA Ọlọrun ní,

3. ‘Ẹ sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn nítorí ọjọ́ burúkú tí ń bọ̀,nítorí ọjọ́ náà súnmọ́lé,ọjọ́ OLUWA ti dé tán,yóo jẹ́ ọjọ́ ìṣúduduati ìparun fún àwọn orílẹ̀-èdè.

Isikiẹli 30