Isikiẹli 3:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn ọmọ Israẹli kò ní gbọ́ tìrẹ, nítorí pé wọn kò fẹ́ gbọ́ ọ̀rọ̀ mi. Olóríkunkun ati ọlọ́kàn líle ni gbogbo wọn.

Isikiẹli 3

Isikiẹli 3:1-12