Isikiẹli 3:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni ẹ̀mí gbé mi dìde, ó sì gbé mi lọ. Tìbínú-tìbínú ni mo sì fi ń lọ. Ẹ̀mí OLUWA ni ó gbé mi lọ pẹlu agbára.

Isikiẹli 3

Isikiẹli 3:11-15