Isikiẹli 29:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, OLUWA Ọlọrun ní: “Wò ó, n óo fi ogun jà yín, n óo sì pa yín run, ati eniyan ati ẹranko.

Isikiẹli 29

Isikiẹli 29:1-18