Isikiẹli 29:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, “Ìwọ ọmọ eniyan, kọjú rẹ sí Farao ọba Ijipti, kí o sì sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa òun ati gbogbo àwọn ará Ijipti pé,

Isikiẹli 29

Isikiẹli 29:1-11