Isikiẹli 29:14 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo dá ire wọn pada, n óo kó wọn pada sí ilẹ̀ Patirosi, níbi tí a bí wọn sí. Wọn óo sì wà níbẹ̀ bí ìjọba tí kò lágbára.

Isikiẹli 29

Isikiẹli 29:12-15