Isikiẹli 29:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Eniyan tabi ẹranko kò ní gba ibẹ̀ kọjá, ẹnikẹ́ni kò ní gbé ibẹ̀ fún ogoji ọdún.

Isikiẹli 29

Isikiẹli 29:8-12