Isikiẹli 28:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo fi kerubu tí a fi àmì òróró yàn tì ọ́. O wà lórí òkè mímọ́ èmi Ọlọrun, o sì ń rìn láàrin àwọn òkúta olówó iyebíye tí ń tàn yinrinyinrin.

Isikiẹli 28

Isikiẹli 28:11-20