Isikiẹli 27:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọkọ̀ Taṣiṣi ní ń bá ọ ru ọjà rẹ lọ ta.Ọjà kún inú rẹ,ẹrù rìn ọ́ mọ́lẹ̀ láàrin omi òkun.

Isikiẹli 27

Isikiẹli 27:17-28