Isikiẹli 27:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Arabia ati àwọn olóyè Kedari ni àwọn oníbàárà rẹ pataki, wọn a máa ra ọ̀dọ́ aguntan, àgbò, ati ewúrẹ́ lọ́wọ́ rẹ.

Isikiẹli 27

Isikiẹli 27:11-28