Isikiẹli 27:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Jafani, Tubali, ati Meṣeki ń bá ọ ṣòwò; wọ́n ń kó ẹrú ati ohun èlò idẹ wá fún ọ, wọn fi ń gba àwọn nǹkan tí ò ń tà.

Isikiẹli 27

Isikiẹli 27:8-16