Isikiẹli 27:10 BIBELI MIMỌ (BM)

“Àwọn ará Pasia ati àwọn ará Ludi ati àwọn ará Puti wà láàrin àwọn ọmọ ogun rẹ bí akọni. Wọ́n gbé asà ati àṣíborí wọn kọ́ sinu rẹ, wọ́n jẹ́ kí o gba ògo.

Isikiẹli 27

Isikiẹli 27:6-13